Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 48:7 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ọwọ́ yóo tẹ ìwọ náà, Moabu, nítorí pé o gbójú lé ibi ààbò ati ọrọ̀ rẹ.Oriṣa Kemoṣi yóo lọ sí ìgbèkùn, pẹlu àwọn babalóòṣà ati àwọn ìjòyè rẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremaya 48

Wo Jeremaya 48:7 ni o tọ