Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 48:39 BIBELI MIMỌ (BM)

A ti fọ́ Moabu túútúú! Ẹ̀ ń sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn! Moabu pẹ̀yìndà pẹlu ìtìjú! Moabu wá di ẹni yẹ̀yẹ́ ati ẹni àríbẹ̀rù fún gbogbo àwọn tí wọ́n yí i ká.”

Ka pipe ipin Jeremaya 48

Wo Jeremaya 48:39 ni o tọ