Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 48:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Moabu, ṣebí ò ń fi Israẹli ṣe yẹ̀yẹ́?Ṣé o bá a láàrin àwọn ọlọ́ṣà ni,tí ó fi jẹ́ pé nígbàkúùgbà tí o bá ń sọ̀rọ̀ rẹ̀, ń ṣe ni o máa ń mi orí rẹ?

Ka pipe ipin Jeremaya 48

Wo Jeremaya 48:27 ni o tọ