Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 48:22-25 BIBELI MIMỌ (BM)

22. Diboni, Nebo, ati Beti Dibilataimu,

23. Kiriataimu, Betigamuli, ati Betimeoni,

24. Kerioti, Bosira, ati gbogbo àwọn ìlú ilẹ̀ Moabu, ati àwọn tí wọ́n wà nítòsí, ati àwọn tí wọ́n wà lókèèrè.

25. Ipá Moabu ti pin, a sì ti ṣẹ́ ẹ lápá. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”

Ka pipe ipin Jeremaya 48