Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 48:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí yóo pa ilẹ̀ Moabu ati àwọn ìlú rẹ̀ run ti dé,àwọn àṣàyàn ọmọkunrin rẹ̀ sì ti lọ sí ibi tí wọn ó ti pa wọ́n.Èmi ọba, tí orúkọ mi ń jẹ́ OLUWA àwọn ọmọ ogun, ni ó sọ bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremaya 48

Wo Jeremaya 48:15 ni o tọ