Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 48:12 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà, àkókò ń bọ̀,tí n óo jẹ́ kí wọn da Moabu nù, bí ẹni da ọtí nù.Àwọn tí wọn ń da ọtí nù ni n óo rán, tí wọn óo wá tẹ̀ ẹ́ bí ìgò ọtíwọn óo dà á nù patapata, wọn óo sì fọ́ ìgò rẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremaya 48

Wo Jeremaya 48:12 ni o tọ