Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 48:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA àwọn ọmọ ogun, Ọlọrun Israẹli sọ nípa Moabu pé,“Nebo gbé nítorí yóo di ahoro!Ojú yóo ti Kiriataimu nítorí ogun óo kó o;ìtìjú yóo bá ibi ààbò rẹ̀, wọn óo wó o lulẹ̀;

Ka pipe ipin Jeremaya 48

Wo Jeremaya 48:1 ni o tọ