Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 46:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó yá, ẹṣin, ẹ gbéra,kí kẹ̀kẹ́ ogun máa sáré kíkankíkan!Kí àwọn ọmọ ogun máa nìṣó,àwọn ọmọ ogun Etiopia ati Puti, tí wọ́n mọ asà á lò,àwọn ọmọ ogun Ludi, tí wọ́n mọ ọfà á ta dáradára.’ ”

Ka pipe ipin Jeremaya 46

Wo Jeremaya 46:9 ni o tọ