Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 46:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Oluwa ní, “Kí ni mo rí yìí?Ẹ̀rù ń bà wọ́n, wọ́n sì ń pada sẹ́yìn.A ti lu àwọn ọmọ ogun wọn bolẹ̀,wọ́n sì ń sálọ pẹlu ìkánjú;wọn kò bojú wẹ̀yìn, ìpayà yí wọn ká!

Ka pipe ipin Jeremaya 46

Wo Jeremaya 46:5 ni o tọ