Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 46:25 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA àwọn ọmọ ogun, Ọlọrun Israẹli ní: “N óo fi ìyà jẹ Amoni, oriṣa Tebesi, ati Farao, ati Ijipti pẹlu àwọn oriṣa rẹ̀, ati àwọn ọba rẹ̀. N óo fìyà jẹ Farao ati àwọn tí wọ́n gbẹ́kẹ̀lé e.

Ka pipe ipin Jeremaya 46

Wo Jeremaya 46:25 ni o tọ