Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 46:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ ogun tí ó fi owó bẹ̀ lọ́wẹ̀,dàbí akọ mààlúù àbọ́pa láàrin rẹ̀;àwọn náà pẹ̀yìndà, wọ́n ti jọ sálọ,wọn kò lè dúró;nítorí ọjọ́ ìdààmú wọn ti dé bá wọn,ọjọ́ ìjìyà wọn ti pé.

Ka pipe ipin Jeremaya 46

Wo Jeremaya 46:21 ni o tọ