Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 46:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀rọ̀ lórí Ijipti: Nípa àwọn ọmọ ogun Farao Neko, ọba Ijipti, tí wọ́n wà létí odò Yufurate ní Kakemiṣi, àwọn tí Nebukadinesari, ọba Babiloni, ṣẹgun ní ọdún kẹrin tí Jehoiakimu ọmọ Josaya jọba Juda.

Ka pipe ipin Jeremaya 46

Wo Jeremaya 46:2 ni o tọ