Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 44:13 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fìyà jẹ àwọn tí wọn ń gbé ilẹ̀ Ijipti, n óo fi ogun, ìyàn, ati àjàkálẹ̀ àrùn pa wọ́n run bí mo ṣe fi pa Jerusalẹmu run.

Ka pipe ipin Jeremaya 44

Wo Jeremaya 44:13 ni o tọ