Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 43:6 BIBELI MIMỌ (BM)

àwọn ọkunrin ati àwọn obinrin, àwọn ọmọde, àwọn ìjòyè, ati gbogbo àwọn tí Nebusaradani, olórí àwọn ẹ̀ṣọ́ ọba Babiloni, fi sábẹ́ àkóso Gedalaya ọmọ Ahikamu, ọmọ Ṣafani, ati Jeremaya wolii ati Baruku ọmọ Neraya.

Ka pipe ipin Jeremaya 43

Wo Jeremaya 43:6 ni o tọ