Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 43:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Asaraya, ọmọ Hoṣaaya, ati Johanani, ọmọ Karea, ati gbogbo àwọn ọkunrin aláfojúdi kan wí fún Jeremaya pé, “Irọ́ ni ò ń pa. OLUWA Ọlọrun wa kò rán ọ láti sọ fún wa pé kí á má lọ ṣe àtìpó ní Ijipti.

Ka pipe ipin Jeremaya 43

Wo Jeremaya 43:2 ni o tọ