Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 42:20 BIBELI MIMỌ (BM)

pé ẹ ti fi ẹ̀mí ara yín wéwu nítorí ìṣìnà yín. Nítorí pé nígbà tí ẹ rán mi sí OLUWA Ọlọrun yín pé kí n gbadura fun yín, gbogbo ohun tí OLUWA Ọlọrun yín bá wí ni kí n sọ fun yín, ẹ ní ẹ óo sì ṣe é.

Ka pipe ipin Jeremaya 42

Wo Jeremaya 42:20 ni o tọ