Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 42:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn tí wọ́n bá gbójú lé àtilọ sí Ijipti láti máa gbé ibẹ̀ yóo kú ikú ogun, ati ti ìyàn pẹlu àjàkálẹ̀ àrùn, wọn kò ní ṣẹ́kù, bẹ́ẹ̀ ni ẹnikẹ́ni wọn kò ní bọ́ ninu ibi tí n óo mú wá sórí wọn.’

Ka pipe ipin Jeremaya 42

Wo Jeremaya 42:17 ni o tọ