Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 41:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Kòtò tí Iṣimaeli ju òkú àwọn eniyan tí ó pa sí ni kòtò tí ọba Asa gbẹ́ tí ó fi dí ọ̀nà mọ́ Baaṣa ọba Israẹli; ṣugbọn Iṣimaeli, ọmọ Netanaya fi òkú eniyan tí ó pa kún kòtò náà.

Ka pipe ipin Jeremaya 41

Wo Jeremaya 41:9 ni o tọ