Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 40:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Jeremaya bá pada sọ́dọ̀ Gedalaya, ọmọ Ahikamu ní Misipa, ó sì ń gbé pẹlu rẹ̀ láàrin àwọn eniyan tí wọn kù ní ilẹ̀ náà.

Ka pipe ipin Jeremaya 40

Wo Jeremaya 40:6 ni o tọ