Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 40:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nebusaradani, olórí àwọn ẹ̀ṣọ́ ọba Babiloni, sọ fún Jeremaya pé, “OLUWA Ọlọrun rẹ ti pinnu láti ṣe ilẹ̀ yìí ní ibi;

Ka pipe ipin Jeremaya 40

Wo Jeremaya 40:2 ni o tọ