Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 40:12 BIBELI MIMỌ (BM)

gbogbo àwọn ará Juda pada láti gbogbo ibi tí wọn sá lọ, wọ́n wá sí ilẹ̀ Juda, wọ́n lọ sí ọ̀dọ̀ Gedalaya ní Misipa, wọ́n sì kó ọtí ati èso jọ lọpọlọpọ.

Ka pipe ipin Jeremaya 40

Wo Jeremaya 40:12 ni o tọ