Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 4:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kọ ara yín ní ilà abẹ́ fún OLUWA, kí ẹ sì kọ ara yín ní ilà ọkàn, ẹ̀yin ará Juda ati ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé Jerusalẹmu; kí ibinu mi má baà dé, bí iná tí ó ń jó tí kò sí ẹni tí ó lè pa á, nítorí iṣẹ́ ibi yín.”

Ka pipe ipin Jeremaya 4

Wo Jeremaya 4:4 ni o tọ