Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 4:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wò ó! Ó ń bọ̀ bí ìkùukùu,kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀ dàbí ìjì.Àwọn ẹṣin rẹ̀ yára ju àṣá lọ.A gbé, nítorí ìparun dé bá wa.

Ka pipe ipin Jeremaya 4

Wo Jeremaya 4:13 ni o tọ