Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 4:11 BIBELI MIMỌ (BM)

A óo wí fún àwọn eniyan yìí, ati àwọn ará Jerusalẹmu ní ìgbà náà pé afẹ́fẹ́ gbígbóná kan ń fẹ́ bọ̀ láti orí àwọn òkè, ninu pápá, ó ń fẹ́ bọ̀ sọ́dọ̀ àwọn eniyan mi; kì í ṣe afẹ́fẹ́ lásán tíí fẹ́ pàǹtí ati ìdọ̀tí dànù.

Ka pipe ipin Jeremaya 4

Wo Jeremaya 4:11 ni o tọ