Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 39:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn ọmọ ogun Kalidea lé wọn, wọ́n bá Sedekaya ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ Jẹriko; wọ́n mú un lọ sí ọ̀dọ̀ Nebukadinesari ọba Babiloni ní Ribila ní ilẹ̀ Hamati, ó sì dá Sedekaya lẹ́jọ́.

Ka pipe ipin Jeremaya 39

Wo Jeremaya 39:5 ni o tọ