Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 38:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn ìjòyè tọ Jeremaya lọ, wọ́n bí í, ó sì fún wọn lésì gẹ́gẹ́ bí ọba tí pàṣẹ fún un. Wọ́n bá dákẹ́, nítorí ẹnikẹ́ni kò gbọ́ ọ̀rọ̀ tí wọ́n jọ sọ.

Ka pipe ipin Jeremaya 38

Wo Jeremaya 38:27 ni o tọ