Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 37:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Jeremaya dá a lóhùn, pé, “Rárá o, n kò sálọ sọ́dọ̀ àwọn ará Kalidea.” Ṣugbọn Irija kọ̀, kò gbọ́, ó sá mú Jeremaya lọ sọ́dọ̀ àwọn ìjòyè.

Ka pipe ipin Jeremaya 37

Wo Jeremaya 37:14 ni o tọ