Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 36:31 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo jẹ òun, ati àwọn ọmọ rẹ̀, ati àwọn ẹmẹ̀wà rẹ̀ níyà, nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn. N óo mú kí gbogbo ibi tí mo pinnu lórí wọn ṣẹ sí wọn lára ati sí ara àwọn tí ń gbé Jerusalẹmu ati àwọn ará Juda, nítorí pé wọn kò gbọ́ràn.”

Ka pipe ipin Jeremaya 36

Wo Jeremaya 36:31 ni o tọ