Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 36:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu oṣù kẹsan-an ni ọ̀rọ̀ yìí ṣẹlẹ̀, ọba sì wà ní ilé tíí máa gbé ní àkókò òtútù, iná kan sì wà níwájú rẹ̀ tí ń jó ninu agbada.

Ka pipe ipin Jeremaya 36

Wo Jeremaya 36:22 ni o tọ