Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 36:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó lọ sí yàrá akọ̀wé ní ààfin ọba, ó bá gbogbo àwọn ìjòyè tí wọn jókòó níbẹ̀: Eliṣama akọ̀wé ati Delaaya ọmọ Ṣemaaya, ati Elinatani ọmọ Akibori, ati Gemaraya ọmọ Ṣafani, ati Sedekaya ọmọ Hananaya ati gbogbo àwọn ìjòyè.

Ka pipe ipin Jeremaya 36

Wo Jeremaya 36:12 ni o tọ