Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 35:8 BIBELI MIMỌ (BM)

A gbọ́ràn sí Jonadabu baba ńlá wa lẹ́nu, à ń pa gbogbo àṣẹ tí ó pa fún wa mọ́, pé kí á má mu ọtí ní gbogbo ọjọ́ ayé wa, àwa, àwọn aya wa ati àwọn ọmọ wa lọkunrin ati lobinrin.

Ka pipe ipin Jeremaya 35

Wo Jeremaya 35:8 ni o tọ