Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 35:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo gbé ìgò ọtí kalẹ̀ níwájú àwọn ọmọ Rekabu, mo kó ife tì í. Mo bá sọ fún wọn pé, “Ó yá, ẹ máa mu ọtí waini.”

Ka pipe ipin Jeremaya 35

Wo Jeremaya 35:5 ni o tọ