Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 35:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nígbà tí Nebukadinesari, ọba Babiloni gbógun ti ilẹ̀ yìí, a wí fún ara wa pé kí á wá sí Jerusalẹmu nítorí ìbẹ̀rù àwọn ọmọ ogun, àwọn ará Kalidea ati ti àwọn ará Siria. Bẹ́ẹ̀ ni a ṣe di ẹni tí ń gbé Jerusalẹmu.”

Ka pipe ipin Jeremaya 35

Wo Jeremaya 35:11 ni o tọ