Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 34:9 BIBELI MIMỌ (BM)

kí olukuluku dá ẹrú rẹ̀, lọkunrin ati lobinrin, tí wọ́n jẹ́ Heberu sílẹ̀, kí wọn máa lọ ní òmìnira; kí ẹnikẹ́ni má sì fi Juu arakunrin rẹ̀ ṣe ẹrú mọ́.

Ka pipe ipin Jeremaya 34

Wo Jeremaya 34:9 ni o tọ