Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 34:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Láìpẹ́ yìí, ẹ ronupiwada, ẹ sì ṣe ohun tí ó tọ́ lójú mi; ẹ kéde ìdásílẹ̀ fún àwọn arakunrin yín. Ẹ dá majẹmu níwájú mi ninu ilé tí à ń fi orúkọ mi pè.

Ka pipe ipin Jeremaya 34

Wo Jeremaya 34:15 ni o tọ