Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 33:26 BIBELI MIMỌ (BM)

òun nìkan ni n óo fi kọ arọmọdọmọ Jakọbu ati Dafidi, iranṣẹ mi sílẹ̀, tí n kò fi ní máa yan ọ̀kan ninu àwọn ọmọ rẹ̀ láti jọba lórí ìran Abrahamu, Isaaki ati Jakọbu. N óo dá ire wọn pada, n óo sì ṣàánú fún wọn.”

Ka pipe ipin Jeremaya 33

Wo Jeremaya 33:26 ni o tọ