Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 33:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tó bá yá, tí àkókò bá tó, n óo mú kí ẹ̀ka òdodo kan ó sọ jáde ní ilé Dafidi, yóo máa ṣe ìdájọ́ ẹ̀tọ́ ati ti òdodo ní ilẹ̀ náà.

Ka pipe ipin Jeremaya 33

Wo Jeremaya 33:15 ni o tọ