Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 33:12 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA àwọn ọmọ ogun sọ pé, “Ní gbogbo ibi tí ó ti di ahoro yìí, tí eniyan tabi ẹranko kò gbé ibẹ̀, àwọn olùṣọ́-aguntan yóo sì tún máa tọ́jú àwọn agbo ẹran wọn ninu gbogbo àwọn ìlú ibẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremaya 33

Wo Jeremaya 33:12 ni o tọ