Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 32:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo máa jẹ́ ohun ayọ̀ fún mi láti ṣe wọ́n lóore, n óo fi tẹ̀mítẹ̀mí ati tọkàntọkàn fi ìdí wọn múlẹ̀ ninu jíjẹ́ olóòótọ́ ní ilẹ̀ yìí.

Ka pipe ipin Jeremaya 32

Wo Jeremaya 32:41 ni o tọ