Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 32:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Sedekaya ọba Juda ni ó sọ Jeremaya sẹ́wọ̀n, ó ní, kí ló dé tí Jeremaya fi sọ àsọtẹ́lẹ̀ pé OLUWA ní òun óo fi Jerusalẹmu lé ọba Babiloni lọ́wọ́, yóo sì gbà á;

Ka pipe ipin Jeremaya 32

Wo Jeremaya 32:3 ni o tọ