Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 32:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará Kalidea tí wọn gbógun ti ìlú yìí, yóo wọ inú rẹ̀, wọn yóo sì dáná sun ún pẹlu àwọn ilẹ̀ tí wọ́n tí ń sun turari sí oriṣa Baali lórí wọn, tí wọ́n sì tí ń rú ẹbọ ohun mímu sí àwọn oriṣa tí wọn ń mú mi bínú.

Ka pipe ipin Jeremaya 32

Wo Jeremaya 32:29 ni o tọ