Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 32:19 BIBELI MIMỌ (BM)

ìwọ Olùdámọ̀ràn ńlá, tí ó lágbára ní ìṣe; ìwọ tí ojú rẹ ń rí sí gbogbo ọ̀nà àwọn ọmọ eniyan, tí o sì ń san ẹ̀san fún olukuluku gẹ́gẹ́ bí ìwà ati iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀;

Ka pipe ipin Jeremaya 32

Wo Jeremaya 32:19 ni o tọ