Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 31:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wò ó! N óo kó wọn wá láti ilẹ̀ àríwá,n óo kó wọn jọ láti òpin ayé.Àwọn afọ́jú ati arọ yóo wà láàrin wọn,ati aboyún ati àwọn tí wọn ń rọbí lọ́wọ́.Ogunlọ́gọ̀ eniyan ni àwọn tí yóo pada wá síbí.

Ka pipe ipin Jeremaya 31

Wo Jeremaya 31:8 ni o tọ