Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 31:37 BIBELI MIMỌ (BM)

Àfi bí eniyan bá lè wọn ojú ọ̀run,tí ó sì lè wádìí ìpìlẹ̀ ayé,ni òun lè ké àwọn ọmọ Israẹli kúrò,nítorí gbogbo ohun tí wọ́n ṣe.

Ka pipe ipin Jeremaya 31

Wo Jeremaya 31:37 ni o tọ