Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 31:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Kì í ṣe irú majẹmu tí mo bá àwọn baba ńlá wọn dá, ní ìgbà tí mo fà wọ́n lọ́wọ́ jáde ní ilẹ̀ Ijipti, àní majẹmu mi tí wọn dà, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé èmi ni ọkọ wọn.

Ka pipe ipin Jeremaya 31

Wo Jeremaya 31:32 ni o tọ