Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 30:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ bèèrè, kí ẹ sì ṣe ìwádìí;ǹjẹ́ ọkunrin lè lóyún kí ó sì bímọ?Kí ló wá dé tí mo rí gbogbo ọkunrin,tí wọn ń dáwọ́ tẹ ìbàdí bí obinrin tí ń rọbí?Kí ló dé tí gbogbo yín fajúro?

Ka pipe ipin Jeremaya 30

Wo Jeremaya 30:6 ni o tọ