Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 30:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Ibinu gbígbóná OLUWA kò ní yipada,títí yóo fi mú èrò ọkàn rẹ̀ ṣẹ.Òye nǹkan wọnyi yóo ye yín ní ọjọ́ ìkẹyìn.

Ka pipe ipin Jeremaya 30

Wo Jeremaya 30:24 ni o tọ