Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 3:8 BIBELI MIMỌ (BM)

ó mọ̀ pé nítorí ìwà àgbèrè Israẹli, alaiṣootọ, ni mo ṣe lé e jáde, tí mo sì kọ̀ ọ́ sílẹ̀. Sibẹsibẹ Juda tí òun pàápàá jẹ́ alaiṣootọ, kò bẹ̀rù, òun náà lọ ṣe àgbèrè.

Ka pipe ipin Jeremaya 3

Wo Jeremaya 3:8 ni o tọ