Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 3:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìtẹ́ OLUWA ni wọ́n óo máa pe Jerusalẹmu nígbà náà. Gbogbo orílẹ̀-èdè yóo parapọ̀ wá sibẹ, níwájú èmi OLUWA, ní Jerusalẹmu, wọn kò ní fi oríkunkun tẹ̀ sí ìmọ̀ burúkú ọkàn wọn mọ́.

Ka pipe ipin Jeremaya 3

Wo Jeremaya 3:17 ni o tọ