Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremaya 3:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣá ti gbà pé o jẹ̀bi,ati pé o ti ṣọ̀tẹ̀ sí èmi OLUWA Ọlọrun rẹ.O ti fi ògo rẹ wọ́lẹ̀ fún àwọn àjèjì oriṣa,lábẹ́ gbogbo igi tútù;o kò sì gbọ́ràn sí mi lẹ́nu.Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.’

Ka pipe ipin Jeremaya 3

Wo Jeremaya 3:13 ni o tọ